Ewi S??r?? So?ke? - Funmilayo Adesanya-Davies - Books - Globeedit - 9786200622136 - April 13, 2021
In case cover and title do not match, the title is correct

Ewi S??r?? So?ke?

Funmilayo Adesanya-Davies

Price
NOK 359
excl. VAT

Ordered from remote warehouse

Expected delivery Oct 7 - 17
Add to your iMusic wish list

Ewi S??r?? So?ke?

EWÌ S??R?? SO?KE? Ó j?? ohùn ìdùnnú fún mí púp?? láti k? ìwé àkój?p?? ewì yìí. Àw?n ewì j? ohun àbálàye tí ó j? ?m? Yorùbá lógún. Ní ayé àtij?? ní ilè Yorùbá, ò un ni àw?n bàbá-?lá wa máa ? lò fún ìmò?, ìmò?ràn àti ??k??, ?ùgbó?n won kìí k??? síl?? nítorí pé, w?n kò ní ìmò? mò?ó?k?-mò?ó?kà rárá. Orísírísí àw?n ewì ni ó wa, Èrò ?kàn mí ní pé a ó gbàdùn ìwé àkój?p?? ewì yìí. "Ewì S??r?? Sókè!" ni àk?lé Ìwé Ì?ípayá Ewi Yorùbá yìí (Poetry On Speak Up!). Àk?lé ìwé yìí j? jáde nínú ??r?? àw?n ??d?? Nàíjíríà (A popular phrase that has informally become the name of the millennial slang of generations in Nigeria). Àw?n ??d?? ?e ìw?de #EndSARS ní Oríl??-èdè Nàíjíríà ní ìpínlè Èkó, Ekiti, ??y??, Ondo, Osun, Kwara ati Abuja lati bá àw?n olórí àti àw?n ?m? ilu s??r?? ní ?dún 2020. Kí ni ìtum?? "S??r?? Sókè" àti Ìw??de tí àw?n ??d?? n ?e àgbékal?? r?? yìí? Wó?n fi Ìw??de #EndSARS yìí s? pé kí àw?n ?l?pa má ?e pa àw?n ará ìlú m??, pàtàkì jù l? àw?n ??d?? àti pé kí olúkúlùkù s? àw?n è?dùn ?kàn w?n gbogbo jáde ni oríl??-èdè NÀÍJÍRÍÀ. Naijiria ni orílè-èdè tí ó ní ibùgbé púpò jùl? ní Afrika, ó tún j?? ìk?j? ní àgbáyé, b? si ní ó j?? oríl??-èdè tó ní àw?n ènìyàn dúdú jùl? pè?lú.

Media Books     Paperback Book   (Book with soft cover and glued back)
Released April 13, 2021
ISBN13 9786200622136
Publishers Globeedit
Pages 76
Dimensions 152 × 229 × 5 mm   ·   131 g
Language Afrikaans  

Show all

More by Funmilayo Adesanya-Davies